Alaroye onlinetv
Alaroye onlinetv
  • Видео 7 015
  • Просмотров 50 075 540

Видео

ỌNA NI ỌMỌBINRIN KAN N BEERE LỌWỌ WISDOM, INU IGBO LO TAN AN LỌ TO TI FIPA ṢE 'KINNI' FUN UN
Просмотров 3373 часа назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
EYI NI BI ORI OKU TI WỌN BA NINU ILE MI ṢE DEBẸ-LEKAN
Просмотров 1,1 тыс.4 часа назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
WỌN TI MU AWỌN ELEYII, ILE ONILE NI WỌN NI FỌ N'ILỌRIN
Просмотров 2735 часов назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
ṢỌUN LO L'OGBOMỌṢỌ NI ABI LEMỌỌMU YII
Просмотров 1,6 тыс.7 часов назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
AWỌN ỌMỌ IBADAN SỌRỌ SOKE: WỌN NI IGBIMỌ TI MAKINDE GBE KALẸ FUN IWUYE OLUBADAN KO DAA TO
Просмотров 1,9 тыс.8 часов назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
ROGBODIYAN BẸ SILẸ NIBI ETO IDIBO ABẸLE APC NI KWARA
Просмотров 7339 часов назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
ÎṢẸ́ KI I PA NI: EGBOOGI OLORO TI ỌMỌKUNRIN YII MU LAMUJU TI ṢEKU PA A
Просмотров 3,4 тыс.10 часов назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
KI ỌLỌMỌ KILỌ F'ỌMO Ẹ AWỌN BOKO HARAM TI TUN DE O!
Просмотров 7 тыс.14 часов назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
IJA ṢỌUN ATI IMAAMU OGBOMỌṢỌ, EYI LOHUN TILE-ẸJỌ SỌ
Просмотров 4,5 тыс.4 часа назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
AJAKALẸ ARUN KỌLẸRA TI WỌ INU ỌGBA KIRIKIRI L'EKOO
Просмотров 6364 часа назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
WỌN TI MU DANIEL, IWEERINNA ẸGBỌN Ẹ TO TI KU LO FẸẸ FI GBE OOGUN OLORO LỌ S'OKE-OKUN
Просмотров 1,9 тыс.4 часа назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
AJINIGBE JI AWỌN ARINRIN-AJO OGUN GBE LỌNA IJẸBU-ODE
Просмотров 3,9 тыс.4 часа назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
AWỌN AGBEBỌN JI PASITỌ GBE NINU OKO RẸ L’ỌGBẸṢẸ
Просмотров 1,7 тыс.4 часа назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
ṢẸYIN NAA TI GBỌ! KO NI I SI INA IJỌBA FUN ODIDI OṢU MEJI GBAKO NIPINLẸ ONDO ATI EKITI
Просмотров 3,4 тыс.4 часа назад
We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
AWỌN EEYAN N BINU SI GOMINA AYEDATIWA L’ONDO, EYI L'OHUN TO ṢE
Просмотров 3,4 тыс.4 часа назад
AWỌN EEYAN N BINU SI GOMINA AYEDATIWA L’ONDO, EYI L'OHUN TO ṢE
ẸWỌN N ṢẸ'WỌ SI HASSAN O, IBỌN NI WỌN KA MỌ ỌN LỌWỌ L’EKOO
Просмотров 8294 часа назад
ẸWỌN N ṢẸ'WỌ SI HASSAN O, IBỌN NI WỌN KA MỌ ỌN LỌWỌ L’EKOO
INU ṢALANGA NI WỌN TI RI OKU ỌMỌ TI WỌN N WA L’EKOO
Просмотров 2,5 тыс.4 часа назад
INU ṢALANGA NI WỌN TI RI OKU ỌMỌ TI WỌN N WA L’EKOO
IGBIMỌ IMAAMU OGBOMỌṢỌ TI SỌRỌ: ṢỌUN LO NI MỌṢALAAṢI, OUN LO GBỌDỌ FI IMAAMU JẸ
Просмотров 9 тыс.4 часа назад
IGBIMỌ IMAAMU OGBOMỌṢỌ TI SỌRỌ: ṢỌUN LO NI MỌṢALAAṢI, OUN LO GBỌDỌ FI IMAAMU JẸ
ILE ẸJỌ TI NI KI ẸBI MOHBAD LỌỌ ṢAYẸWO ỌMỌ WỌN NIBI TI WỌN BA NIFẸẸ SI
Просмотров 3,1 тыс.7 часов назад
ILE ẸJỌ TI NI KI ẸBI MOHBAD LỌỌ ṢAYẸWO ỌMỌ WỌN NIBI TI WỌN BA NIFẸẸ SI
EYI NI ỌNA TUNTUN TI NDLEA YOO MAA GBA GBOGUN TI AWỌN ONIṢOWO EGBOOGI OLORO
Просмотров 1,8 тыс.7 часов назад
EYI NI ỌNA TUNTUN TI NDLEA YOO MAA GBA GBOGUN TI AWỌN ONIṢOWO EGBOOGI OLORO
ṢẸYIN NAA TI GBỌ OHUN TAWỌN EEYAN ṢE NITORI MOHBAD L’AMẸRIKA
Просмотров 7 тыс.7 часов назад
ṢẸYIN NAA TI GBỌ OHUN TAWỌN EEYAN ṢE NITORI MOHBAD L’AMẸRIKA
O ṢẸLẸ, IJA NLA DE LAARIN ṢOUN ATI IMAAMU OGBOMỌṢỌ
Просмотров 9 тыс.7 часов назад
O ṢẸLẸ, IJA NLA DE LAARIN ṢOUN ATI IMAAMU OGBOMỌṢỌ
ỌMỌỌDỌ YII DẸ ADIGUNJALE SI ỌGA Ẹ N’IFAKI-EKITI, WỌN GBOWO NLA LỌWỌ Ẹ
Просмотров 3,3 тыс.7 часов назад
ỌMỌỌDỌ YII DẸ ADIGUNJALE SI ỌGA Ẹ N’IFAKI-EKITI, WỌN GBOWO NLA LỌWỌ Ẹ
MACARONI GBA ỌMỌỌṢẸ SANWO-OLU NI GBOLOHUN, L'AWỌN EEYAN BA LO DISAAFU Ẹ
Просмотров 8 тыс.7 часов назад
MACARONI GBA ỌMỌỌṢẸ SANWO-OLU NI GBOLOHUN, L'AWỌN EEYAN BA LO DISAAFU Ẹ
IDAAMU BABA IJẸṢA: ṢẸYIN NAA TI GBỌ OHUN TO ṢẸLẸ SI OṢERE NAA
Просмотров 13 тыс.7 часов назад
IDAAMU BABA IJẸṢA: ṢẸYIN NAA TI GBỌ OHUN TO ṢẸLẸ SI OṢERE NAA
TINUBU, BẸẸ ṢE FẸẸ ṢE E YII GAN-AN LO DAA O
Просмотров 10 тыс.7 часов назад
TINUBU, BẸẸ ṢE FẸẸ ṢE E YII GAN-AN LO DAA O
ṢẸYIN NAA TI GBỌ OHUN TO ṢẸLẸ SI YINKA QUADRI, LAIDE BAKARE, SỌJI ỌMỌ BANKẸ...
Просмотров 10 тыс.9 часов назад
ṢẸYIN NAA TI GBỌ OHUN TO ṢẸLẸ SI YINKA QUADRI, LAIDE BAKARE, SỌJI ỌMỌ BANKẸ...
ERE ASAPAJUDE DA ẸMI EEYAN KAN LEGBODO LORI BIRIIJI EKO KẸTA
Просмотров 3,7 тыс.9 часов назад
ERE ASAPAJUDE DA ẸMI EEYAN KAN LEGBODO LORI BIRIIJI EKO KẸTA
ỌPẸ O! MAKINDE TI GBA LATI GBE ỌPA AṢẸ FUN ỌLAKULẸHIN GẸGẸ BÍI OLUBADAN
Просмотров 3,3 тыс.9 часов назад
ỌPẸ O! MAKINDE TI GBA LATI GBE ỌPA AṢẸ FUN ỌLAKULẸHIN GẸGẸ BÍI OLUBADAN

Комментарии

  • @DAHRULHAQQ
    @DAHRULHAQQ 2 часа назад

    Oba Loni ilu 😅😅 B4 the colonialism oo not now oo9 😊😅 ALAROYE KONI DAAAFUN OOOOO

  • @DAHRULHAQQ
    @DAHRULHAQQ 2 часа назад

    Alaroye Ani Eleribu Ni Yin Sheee

  • @DAHRULHAQQ
    @DAHRULHAQQ 2 часа назад

    SOUN OMO INDIA 😅😅😅

  • @DAHRULHAQQ
    @DAHRULHAQQ 2 часа назад

    ARE ALAOBI 🤣🤣🤣. Plz whenever u want to address Imam put Dr in it

  • @RazeedAyinki
    @RazeedAyinki 3 часа назад

    Olorun osaun wa

  • @adeyojukenny5614
    @adeyojukenny5614 3 часа назад

    Ti obamo nipa e olorun a yoe

  • @abdulwahabahmad4983
    @abdulwahabahmad4983 3 часа назад

    Mama! Ninu Awon Ololufe yin gidi nimi, Sugbon eyi ti eso yii, oku die kaato.

  • @idrisbalogun9191
    @idrisbalogun9191 4 часа назад

    😂

  • @opeyemialways6881
    @opeyemialways6881 4 часа назад

    Ogun Owo State

  • @olatemitope737
    @olatemitope737 4 часа назад

    Ogun state! Ogun state !! Ogun state!!!

  • @olajideoluwayomi6529
    @olajideoluwayomi6529 4 часа назад

    Ẹyin ọdọmọde ẹ dẹ́kun Ògùn olóró ni mímú, ki ẹ ma ba ku ikú àìtó jọ

  • @mustaphaalibagu2662
    @mustaphaalibagu2662 4 часа назад

    🌶🌶🤣🤣🤣🤣

  • @user-vx2py3yy6z
    @user-vx2py3yy6z 5 часов назад

    Soun omo india ni

  • @sherifatagbabiaka8284
    @sherifatagbabiaka8284 5 часов назад

    Se baba Gagaba president Nigeria won gbo gbogbo in kon to sele o ma wa dojue bayi.yoruba e jawo ninu Ote ife se pataki.Alaroye Thank you so much,Oluwa koni ka oju anu e kuro lara yin ni oruko Jesu KRIST 🙏❤️

  • @Adugbo
    @Adugbo 5 часов назад

    Alaroye e ti yawere. Tani soun. Imamu ni Baba soun . E so fun soun KO lo sun.

    • @johnjanusek6953
      @johnjanusek6953 3 часа назад

      Don't you have ears ni ? They said the problem is from the family and Muslim communities. They said he's been having issues with the former king before this new king, so what's the color of your problem? Religion has really blinded you that you can't listen to facts.

  • @adeyemiyusuff6458
    @adeyemiyusuff6458 5 часов назад

    You don't get it right in this OSOJUMI KORO

  • @abdullateefarije-cy3qp
    @abdullateefarije-cy3qp 5 часов назад

    Soun yawere ni

  • @LukmanAgbaje
    @LukmanAgbaje 6 часов назад

    Ebi ati iya lefin sere yi

  • @olaniyiogundipe3747
    @olaniyiogundipe3747 6 часов назад

    Controversial Imam Yinus need to be remove with all possible means, to be able to have peace in Ogbomoso and Yoruba at large. This yinus is working together with Ogbomoso and Yoruba enemy, like mufti iwo omo Igbira. Yoruba enemy are in support of this Yinus, to be able to enter us, through religion, to carry out their plan atrocities. Also Ogbomoso people need to arrest this mufti iwo omo Igbira without delay, for giving Soun 7day ultimatum, for what he know nothing about and that does not concern him. imam Yinus is Scam, fake and fraud.

  • @AbiodunIdris-j3s
    @AbiodunIdris-j3s 6 часов назад

    Ooni lakaye

  • @victoriaadebayo6446
    @victoriaadebayo6446 7 часов назад

    Mo jeri Iya Alaroye Lori eto O SE OJU MI KORO ogidi oro pelu lakaye ti o pe ye ni oro yi fun ologbon enia. Kare o mama.

  • @alfirdawstv7281
    @alfirdawstv7281 7 часов назад

    Ogbadun oloo hum asin. Imamu ni baba oba

  • @sakenatafolabi8666
    @sakenatafolabi8666 7 часов назад

    ODODO ORO PANUBELE NI AWON MANGAJI IBADAN PARAPO SO👌

  • @oyewole5530
    @oyewole5530 7 часов назад

    International community can not be of any help to us, and this present-day government will not do anything about security because our vice president is toothless Shettima, aka boko aram commandant, so we are in serious danger

  • @odunayoremilekun7444
    @odunayoremilekun7444 7 часов назад

    Alabuku Baba asete ni Lemoomu yii

  • @LawalKazeem-dd5hj
    @LawalKazeem-dd5hj 7 часов назад

    Eni awi fun oba jekogbo, hmmmmm oga o, won kiun gboroo

  • @asifahmed2639
    @asifahmed2639 7 часов назад

    The alfa is pushing this false narrative to support their great Islamic leader, Shehu Alimi. As a Muslim you have a duty to support, defend and promote anything Islamic, whether it is an Islamic leader or the religion itself. Your first allegiance is to your religion before your family, your country or your tribe. Islam comes first. You are bound to defend Islam by any means necessary even if you have to tell a lie. It is called Taqqiyah. In fact, without lies Islam dies.

  • @abdulkarimsalman
    @abdulkarimsalman 7 часов назад

    Kini e fe gba Lori nkan wanyi,Ni igba ti wan Ti fi je asaju,e gba pe eni ti Olohun Yan nu,ki Ohun na fi Owo sowopo pelu oba ilu,

  • @AjayiKehinde-wx4ej
    @AjayiKehinde-wx4ej 7 часов назад

    My brother God will intervene

  • @adiokem
    @adiokem 7 часов назад

    One spanner lost😂

  • @abdulkarimsalman
    @abdulkarimsalman 7 часов назад

    Eyin alalufa Ogbomosho,E dakun e Pana ote yi,E je ka fi ewa esin alaafiya han, Alaroye eku igbiyanju Oluwa alaanu julo yio sanyin lesan daradara,

  • @abdulkarimsalman
    @abdulkarimsalman 7 часов назад

    Eyin alalufa Ogbomosho,E dakun e Pana ote yi,E je ka fi ewa esin alaafiya han, Alaroye eku igbiyanju Oluwa alaanu julo yio sanyin lesan daradara,

  • @aadeoyemosun0359
    @aadeoyemosun0359 7 часов назад

    Kin ni o kan imam ati iseese po?

  • @giveway...6838
    @giveway...6838 8 часов назад

    Awon Obi ! Ma mi isimi dada bayi

  • @user-fp1pz2gg8x
    @user-fp1pz2gg8x 9 часов назад

    JUSTICE FOR MOHBAD IMOLE FREE ARIFA AND VERNON JUSTICE😂😂😂

  • @AdekunleZainab-yt7tk
    @AdekunleZainab-yt7tk 9 часов назад

    Hummn egbe buburu ni nba iwa rere je 😎

  • @classyjoyce5452
    @classyjoyce5452 9 часов назад

    Hope they will not give them bill for that two months

  • @Iba-Olorun55
    @Iba-Olorun55 9 часов назад

    No sense whatsoever in this your stupid news

  • @user-sn8zd4yj1c
    @user-sn8zd4yj1c 9 часов назад

    Eku eto irovin sa Ki tinubu pase ki won lma lo si ilu won Won ki se omo orile ede Nigeria

  • @mariamasie9329
    @mariamasie9329 10 часов назад

    Omase oo

  • @oluwaseunadebowale3504
    @oluwaseunadebowale3504 10 часов назад

    Omase o... Ki olorun sanu awon odo WA ni orile ede naijiria Isowo ti awon odo SE nmu egbogi oloro ti poju

  • @ramonoba4911
    @ramonoba4911 10 часов назад

    BOLA TINUBU IS PLANNING OF 2027 ELECTIONS RIGGING WITH WIKE OGORO MINSTER IN ABUJA

  • @ramonoba4911
    @ramonoba4911 10 часов назад

    BOLA TINUBU A BAG OFF RICE NOW 80k in LOSSES COUNTRY

  • @talithakoum6576
    @talithakoum6576 10 часов назад

    Ewe ti ewure mo je lo ma pa. Oloriburuku omo.

  • @oluwatoyinfadekemi5229
    @oluwatoyinfadekemi5229 11 часов назад

    GOD will fight for mohbad ,please LORD gives justice ⚖️ for mohbad

  • @user-fp1pz2gg8x
    @user-fp1pz2gg8x 11 часов назад

    O MA SE OOO RIP🙏

  • @roselinebolanle9404
    @roselinebolanle9404 11 часов назад

    What are the government doing in Nigeria?how long are we going to live in fear 👧🏾

  • @classyjoyce5452
    @classyjoyce5452 12 часов назад

    What did Nigeria do to deserve all this wickedness God please save us

  • @AjokeOmolare
    @AjokeOmolare 12 часов назад

    Alaseju

  • @buharikabiru9760
    @buharikabiru9760 13 часов назад

    Thankyou God❤